IBI JESU KRISTI
-
Gво akete orun ndùn,
Ogo ni f’Oba titun,
Anu, ‘lafia laiye
Oba orun mba wa gbe. - Gbogbo aiye ji layò,
Pemo orin loke po,
Kí Oba alafia,
Kí örun ododo nã - On fogo rẹ s’apakan,
Abi (i) k’enia má kú mọ,
Abi (i) da elese si,
Abi (i) k’ale tun wa bi. - Wá, Ife araiye, wá!
Wá, gbe inu okàn wa!
Iru obiri ni ji!
K’ofo ejo na lori! - Ogo ni f’oba titun,
K’afi gbogbo orin dun,
Anu ‘lafia laiye
Oba orun mba wa gbe.