More

    ORIN 5 – Aferi Ojo Isimi

    AFERI OJO ISIMI

    1. ABE aferi ‘o
      Ojo ‘simi dara:
      Gbogbo ose ama wi pe,
      Iwo oti pe to!
    2. Okó wa bi Kristi
      Jinde ninu iku:
      Gbogbo ose ama wi pe,
      Iwo oti pę to!
    3. ‘Oso t’ajinde wa
      Gege bi ti Jesu :
      Gbogbo ose ama wi pe,
      Iwo oti pę to!

    4. Iwọ sọ t’isimi
      Tilu alufia
      T’ ibukun enia mimó:
      Iwo oti pe to !