More

    ORIN 18 – Mo wi fun olukuluku

    Hymn 18 – Mo wi fun olukuluku

    1. Mo wi fun olukuluku
      Pe, On ji osiyè,
      Osi wà larin wa pelu,
      Nipa Emi iyè.
    2. Ewi fun enikeji nyin,
      Ki nwọn ji pẹlu wa,
      K’ imole kowa kakiri
      Ni gbogbo aiye wa.
    3. Nisisiyi aiyé yi ri
      Bi ile Baba wa,
      Iyè titun ti on fun ni,
      Oso (o) d’ilé Baba.
    4. Sinu okun ti ojin ju
      Iberu iku bọ,
      Ki gbogbo wa k’ole f’oju
      Ba nkankan ti ombo.
    5. Ona õkun ti On fi rin,
      Mu ni lọ si orun,
      Eni t’orin bi On ti nrin,
      Yio d’odọ rẹ lọrun.
    6. On yè, osi wà pẹlu wa
      Ni gbogbo aiyé yi,
      Ati nigba t’af’ara wa
      F’erupę n’ireti.