More

    OJO ISIMI – Hymn 6

    Orin 6

    1. NIGBAWO, Olugbala mi,
      Ngo ri o ni pipe
      N’ibukun t’ojo isimi
      Laini boju larin.
    2. Ran mi, gba mi ni ‘rinkiri
      Laiye aniyan yi,
      Se ki nf’ife be ebe mi,
      Si gbọ adua mi.
    3. Baba fi Emi re fun mi,
      Oluto at’oré,
      T’otan ipa mi s’ayò, si
      Isimi ailopin.