OJO ISIMI
- NIGBAWO, Olugbala mi,
Ngo ri o ni pipe
N’ibukun t’ojo isimi
Laini boju larin. - Ran mi, gba mi ni ‘rinkiri
Laiye aniyan yi,
Se ki nf’ife be ebe mi,
Si gbọ adua mi -
Baba fi Emi re fun mi,
Oluto at’oré,
T’otan ipa mi s’ayò, si
Isimi ailopin.