AFERI OJO ISIMI
- ABE aferi ‘o
Ojo ‘simi dara:
Gbogbo ose ama wi pe,
Iwo oti pe to! - Okó wa bi Kristi
Jinde ninu iku:
Gbogbo ose ama wi pe,
Iwo oti pę to! -
‘Oso t’ajinde wa
Gege bi ti Jesu :
Gbogbo ose ama wi pe,
Iwo oti pę to! -
Iwọ sọ t’isimi
Tilu alufia
T’ ibukun enia mimó:
Iwo oti pe to !