ORIN ALE.
- Lojo yi ifẹ rẹ gba wa,
Lare l’awa lo simi,
La oru ja k’ iwo gba wa,
Ninu ota da wa si;Jesu se oluso wa,
Le iwo l’agbeke wa. - Ero at’ alejo l’awa
Laiye larin otã nì,
Pa awa ati t’awa mo,
Lapa re l’awa simi;
Nigba t’aiye wa opin
K’aba ‘o gbe nikęhin.